R81.21

Resource Description

‘Baba Mi Jẹ́’ is a heartwarming book that teaches little readers about the love they have for their fathers. Through twenty beautiful reasons, this charming story showcases the many ways a father’s love supports and nurtures a child. Written in both English and Afrikaans, it invites young readers to discover the special bond they share with their dads.

Perfect for children aged 5 and up, “Baba Mi Jẹ́” combines engaging illustrations with simple language, making it an enjoyable read for early learners. This book encourages children to express their feelings and appreciate the everyday moments that make their relationship with their fathers so special.

A wonderful addition to any child’s bookshelf, it’s a celebration of love, family, and the magic of being together.

””””””””””””””””””””””””’

Baba Mi Jẹ́” jẹ́ ìwé tí ń kọ́ àwọn ọmọ kékeré nípa ìfẹ́ tí wọ́n ní sí àwọn bàbá wọn. Nípasẹ̀ ṣiṣe afihan àwọn ìdí méjìlélọ́gọ́rin tó lẹ́wa, ìtàn yìí tọ́ka sí ọpọlọpọ àwọn ọ̀nà tí ìfẹ́ bàbá ṣe ń ṣe àtìlẹ́yìn àti tọ́jú ọmọ. A kọ ìwé yìí ní Ede Gẹẹsi àti Yoruba, ó sì pe àwọn ọmọ kékeré láti ṣàwárí ìbáṣepọ̀ pataki tí wọ́n ní pẹ̀lú bàbá wọn.

Ó péye fún àwọn ọmọ tó wà láàárín ọdún marun-un àti siwaju. “Baba Mi Jẹ́” da àwòrán tó ń fa ni mọra, eyi jẹ́ kí ó rọrùn láti ka fún àwọn ọmọ tó ṣẹ̀ẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iwe kika. Ìwé yìí ń kọ́ àwọn ọmọ láti fi ìmọ̀lára wọn hàn àti láti yà àwọn ìgbà tí wọn ni ìbáṣepọ̀ rere pẹ̀lú bàbá wọn si ọtọ nitori awọn igba naa jẹ́ pàtàkì.

Ìwé yi je iwe tó dára láti fi kún àkójọpọ̀ ìwé ọmọ, ó jẹ́ àjọyọ̀-yẹyẹ-ìfẹ́, ẹbí, àti ìmọ̀lára tí a ní nígbà tí a wà pẹ̀lú ara wa.

 

Resource Reviews

Store reviews: ( 0 ratings )

No ratings have been submitted for this seller yet.
Delete Confirmation
×

Always update your resources, rather than deleting and re-uploading a new one: If a resource is deleted from the system, those that have paid for the resource are no longer able to access their bought product.